Surah Aal-e-Imran Verse 198 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranلَٰكِنِ ٱلَّذِينَ ٱتَّقَوۡاْ رَبَّهُمۡ لَهُمۡ جَنَّـٰتٞ تَجۡرِي مِن تَحۡتِهَا ٱلۡأَنۡهَٰرُ خَٰلِدِينَ فِيهَا نُزُلٗا مِّنۡ عِندِ ٱللَّهِۗ وَمَا عِندَ ٱللَّهِ خَيۡرٞ لِّلۡأَبۡرَارِ
Sugbon awon t’o beru Oluwa won, awon Ogba Idera ti awon odo n san ni isale re n be fun won. Olusegbere ni won ninu re. Ibudesi kan ni lati odo Allahu. Ohun ti n be lodo Allahu si loore julo fun awon eni rere