Surah Aal-e-Imran Verse 199 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranوَإِنَّ مِنۡ أَهۡلِ ٱلۡكِتَٰبِ لَمَن يُؤۡمِنُ بِٱللَّهِ وَمَآ أُنزِلَ إِلَيۡكُمۡ وَمَآ أُنزِلَ إِلَيۡهِمۡ خَٰشِعِينَ لِلَّهِ لَا يَشۡتَرُونَ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ ثَمَنٗا قَلِيلًاۚ أُوْلَـٰٓئِكَ لَهُمۡ أَجۡرُهُمۡ عِندَ رَبِّهِمۡۗ إِنَّ ٱللَّهَ سَرِيعُ ٱلۡحِسَابِ
Dajudaju o n be ninu awon ahlul-kitab eni t’o gbagbo ninu Allahu, ati ohun ti A sokale fun yin ati ohun ti A sokale fun won; won n paya Allahu, won ki i ta awon oro Allahu ni owo kekere. Awon wonyen ni esan lodo Oluwa won. Dajudaju Allahu ni Oluyara nibi isiro-ise