Surah An-Nisa Verse 83 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaوَإِذَا جَآءَهُمۡ أَمۡرٞ مِّنَ ٱلۡأَمۡنِ أَوِ ٱلۡخَوۡفِ أَذَاعُواْ بِهِۦۖ وَلَوۡ رَدُّوهُ إِلَى ٱلرَّسُولِ وَإِلَىٰٓ أُوْلِي ٱلۡأَمۡرِ مِنۡهُمۡ لَعَلِمَهُ ٱلَّذِينَ يَسۡتَنۢبِطُونَهُۥ مِنۡهُمۡۗ وَلَوۡلَا فَضۡلُ ٱللَّهِ عَلَيۡكُمۡ وَرَحۡمَتُهُۥ لَٱتَّبَعۡتُمُ ٱلشَّيۡطَٰنَ إِلَّا قَلِيلٗا
Nigba ti oro ifayabale tabi ipaya kan ba de ba won, won si maa tan an kale. Ti o ba je pe won seri re si (oro) Ojise ati awon alase (iyen, awon onimo esin) ninu won, awon t’o n yo ododo jade ninu oro ninu won iba mo on. Ti ki i ba se oore ajulo Allahu ati aanu Re lori yin ni, eyin iba tele Esu afi iba die (ninu yin)