Surah An-Nisa Verse 84 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaفَقَٰتِلۡ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِ لَا تُكَلَّفُ إِلَّا نَفۡسَكَۚ وَحَرِّضِ ٱلۡمُؤۡمِنِينَۖ عَسَى ٱللَّهُ أَن يَكُفَّ بَأۡسَ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْۚ وَٱللَّهُ أَشَدُّ بَأۡسٗا وَأَشَدُّ تَنكِيلٗا
Nitori naa, jagun fun esin Allahu. Won ko la a bo eni kan lorun afi iwo. Ki o si gbe awon onigbagbo ododo longbe ogun esin jija. O see se ki Allahu ka owoja awon t’o sai gbagbo duro. Ati pe Allahu le julo (nibi) ija. O si le julo nibi ijeni-niya