Surah Al-Maeda Verse 105 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaيَـٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ عَلَيۡكُمۡ أَنفُسَكُمۡۖ لَا يَضُرُّكُم مَّن ضَلَّ إِذَا ٱهۡتَدَيۡتُمۡۚ إِلَى ٱللَّهِ مَرۡجِعُكُمۡ جَمِيعٗا فَيُنَبِّئُكُم بِمَا كُنتُمۡ تَعۡمَلُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, emi ara yin dowo yin. Eni ti o ti sina ko le ko inira ba yin nigba ti e ba ti mona. Odo Allahu ni ibupadasi gbogbo yin patapata. Nigba naa, O maa fun yin ni iro ohun ti e n se nise