Surah Al-Maeda Verse 106 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaيَـٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ شَهَٰدَةُ بَيۡنِكُمۡ إِذَا حَضَرَ أَحَدَكُمُ ٱلۡمَوۡتُ حِينَ ٱلۡوَصِيَّةِ ٱثۡنَانِ ذَوَا عَدۡلٖ مِّنكُمۡ أَوۡ ءَاخَرَانِ مِنۡ غَيۡرِكُمۡ إِنۡ أَنتُمۡ ضَرَبۡتُمۡ فِي ٱلۡأَرۡضِ فَأَصَٰبَتۡكُم مُّصِيبَةُ ٱلۡمَوۡتِۚ تَحۡبِسُونَهُمَا مِنۢ بَعۡدِ ٱلصَّلَوٰةِ فَيُقۡسِمَانِ بِٱللَّهِ إِنِ ٱرۡتَبۡتُمۡ لَا نَشۡتَرِي بِهِۦ ثَمَنٗا وَلَوۡ كَانَ ذَا قُرۡبَىٰ وَلَا نَكۡتُمُ شَهَٰدَةَ ٱللَّهِ إِنَّآ إِذٗا لَّمِنَ ٱلۡأٓثِمِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, (e wa) eri jije laaarin yin nigba ti (ipokaka) iku ba de ba eni kan ninu yin ti o fe so asoole. (E wa) onideede meji ninu yin. Tabi awon meji miiran yato si yin ti eyin ba wa lori irin-ajo ti ajalu iku ba fe sele si yin. E da awon mejeeji duro leyin irun, ki won fi Allahu bura, ti e ba seyemeji (si ododo won, ki won si so pe:) "A o nii ta ibura wa ni iye kan kan, koda ko je ebi. A o si nii fi eri jije ti Allahu (pa lase) pamo. (Bi bee ko) nigba naa, dajudaju awa wa ninu awon elese