Surah Al-Maeda Verse 107 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaفَإِنۡ عُثِرَ عَلَىٰٓ أَنَّهُمَا ٱسۡتَحَقَّآ إِثۡمٗا فَـَٔاخَرَانِ يَقُومَانِ مَقَامَهُمَا مِنَ ٱلَّذِينَ ٱسۡتَحَقَّ عَلَيۡهِمُ ٱلۡأَوۡلَيَٰنِ فَيُقۡسِمَانِ بِٱللَّهِ لَشَهَٰدَتُنَآ أَحَقُّ مِن شَهَٰدَتِهِمَا وَمَا ٱعۡتَدَيۡنَآ إِنَّآ إِذٗا لَّمِنَ ٱلظَّـٰلِمِينَ
Ti won ba si ri i pe awon mejeeji da ese (nipa yiyi asoole pada), ki awon meji miiran ninu awon ti awon mejeeji akoko se abosi si (iyen, ebi oku) ropo won. Ki awon naa si fi Allahu bura pe: "Dajudaju eri jije tiwa je ododo ju eri jije ti awon mejeeji (akoko). A o si nii tayo enu-ala. (Bi bee ko) nigba naa, dajudaju a ti wa ninu awon alabosi