Surah Al-Maeda Verse 109 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maeda۞يَوۡمَ يَجۡمَعُ ٱللَّهُ ٱلرُّسُلَ فَيَقُولُ مَاذَآ أُجِبۡتُمۡۖ قَالُواْ لَا عِلۡمَ لَنَآۖ إِنَّكَ أَنتَ عَلَّـٰمُ ٱلۡغُيُوبِ
Ni ojo ti Allahu yoo ko awon Ojise jo, O si maa so pe: “Ki ni esi ti won fun yin?” Won a so pe: “Ko si imo kan fun wa (nipa re). Dajudaju Iwo, Iwo ni Onimo nipa awon ikoko.”