وَكُلُواْ مِمَّا رَزَقَكُمُ ٱللَّهُ حَلَٰلٗا طَيِّبٗاۚ وَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ ٱلَّذِيٓ أَنتُم بِهِۦ مُؤۡمِنُونَ
E je nnkan eto t’o dara ninu ohun ti Allahu se ni arisiki fun yin. Ati pe e beru Allahu, Eni ti eyin gbagbo ninu Re
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni