Surah Al-Anaam Verse 19 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamقُلۡ أَيُّ شَيۡءٍ أَكۡبَرُ شَهَٰدَةٗۖ قُلِ ٱللَّهُۖ شَهِيدُۢ بَيۡنِي وَبَيۡنَكُمۡۚ وَأُوحِيَ إِلَيَّ هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانُ لِأُنذِرَكُم بِهِۦ وَمَنۢ بَلَغَۚ أَئِنَّكُمۡ لَتَشۡهَدُونَ أَنَّ مَعَ ٱللَّهِ ءَالِهَةً أُخۡرَىٰۚ قُل لَّآ أَشۡهَدُۚ قُلۡ إِنَّمَا هُوَ إِلَٰهٞ وَٰحِدٞ وَإِنَّنِي بَرِيٓءٞ مِّمَّا تُشۡرِكُونَ
So pe: “Ki ni ohun ti o tobi julo ni eri?” So pe: “Allahu ni Elerii laaarin emi ati eyin.” O si fi imisi al-Ƙur’an yii ranse si mi, nitori ki ng le fi se ikilo fun eyin ati enikeni ti (al-Ƙur’an) ba de eti igbo re. Se dajudaju eyin n jerii pe awon olohun miiran tun wa pelu Allahu ni? So pe: “Emi ko nii jerii bee.” So pe: “Oun nikan ni Olohun Okan soso ti ijosin to si. Ati pe dajudaju emi yowo yose ninu ohun ti e n fi sebo (si Allahu).”