ٱلَّذِينَ ءَاتَيۡنَٰهُمُ ٱلۡكِتَٰبَ يَعۡرِفُونَهُۥ كَمَا يَعۡرِفُونَ أَبۡنَآءَهُمُۘ ٱلَّذِينَ خَسِرُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ فَهُمۡ لَا يُؤۡمِنُونَ
Awon ti A fun ni Tira, won mo on gege bi won se mo awon omo won. Awon t’o se emi won lofo (sinu aigbagbo), won ko si nii gbagbo
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni