Surah Al-Anaam Verse 34 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَلَقَدۡ كُذِّبَتۡ رُسُلٞ مِّن قَبۡلِكَ فَصَبَرُواْ عَلَىٰ مَا كُذِّبُواْ وَأُوذُواْ حَتَّىٰٓ أَتَىٰهُمۡ نَصۡرُنَاۚ وَلَا مُبَدِّلَ لِكَلِمَٰتِ ٱللَّهِۚ وَلَقَدۡ جَآءَكَ مِن نَّبَإِيْ ٱلۡمُرۡسَلِينَ
Won kuku ti pe awon Ojise kan lopuro siwaju re. Won si se suuru lori nnkan ti won fi pe won ni opuro. Won si fi inira kan won titi di igba ti aranse Wa fi de ba won. Ko si si alayiipada kan fun awon oro Allahu. Dajudaju iro awon Ojise ti de ba o