Surah Al-Anaam Verse 35 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَإِن كَانَ كَبُرَ عَلَيۡكَ إِعۡرَاضُهُمۡ فَإِنِ ٱسۡتَطَعۡتَ أَن تَبۡتَغِيَ نَفَقٗا فِي ٱلۡأَرۡضِ أَوۡ سُلَّمٗا فِي ٱلسَّمَآءِ فَتَأۡتِيَهُم بِـَٔايَةٖۚ وَلَوۡ شَآءَ ٱللَّهُ لَجَمَعَهُمۡ عَلَى ٱلۡهُدَىٰۚ فَلَا تَكُونَنَّ مِنَ ٱلۡجَٰهِلِينَ
Ti o ba si je pe gbigbunri won lagbara lara re, nigba naa ti o ba lagbara lati wa iho kan sinu (aja) ile, tabi akaba kan sinu sanmo (se bee) ki o le mu ami kan wa fun won. Ati pe ti o ba je pe Allahu ba fe, dajudaju iba ko won jo sinu imona (’Islam). Nitori naa, o o gbodo wa lara awon alaimokan