Surah Al-Anaam Verse 61 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَهُوَ ٱلۡقَاهِرُ فَوۡقَ عِبَادِهِۦۖ وَيُرۡسِلُ عَلَيۡكُمۡ حَفَظَةً حَتَّىٰٓ إِذَا جَآءَ أَحَدَكُمُ ٱلۡمَوۡتُ تَوَفَّتۡهُ رُسُلُنَا وَهُمۡ لَا يُفَرِّطُونَ
Oun ni Olubori t’O wa loke awon eru Re. O si n ran awon eso kan si yin titi di igba ti iku yoo fi de ba eni kookan yin. Awon Ojise wa yo si gba emi re, won ko si nii jafira