ثُمَّ رُدُّوٓاْ إِلَى ٱللَّهِ مَوۡلَىٰهُمُ ٱلۡحَقِّۚ أَلَا لَهُ ٱلۡحُكۡمُ وَهُوَ أَسۡرَعُ ٱلۡحَٰسِبِينَ
Lẹ́yìn náà, wọ́n yóò dá wọn padà sí ọ̀dọ̀ Allāhu, Olúwa wọn, Òdodo. Kíyè sí i, tiRẹ̀ ni ìdájọ́. Òun sì yára jùlọ nínú àwọn olùṣírò
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni