Surah Al-Qaria - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
ٱلۡقَارِعَةُ
Akoko ijaya
Surah Al-Qaria, Verse 1
مَا ٱلۡقَارِعَةُ
Ki ni Akoko ijaya
Surah Al-Qaria, Verse 2
وَمَآ أَدۡرَىٰكَ مَا ٱلۡقَارِعَةُ
Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya
Surah Al-Qaria, Verse 3
يَوۡمَ يَكُونُ ٱلنَّاسُ كَٱلۡفَرَاشِ ٱلۡمَبۡثُوثِ
(Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita
Surah Al-Qaria, Verse 4
وَتَكُونُ ٱلۡجِبَالُ كَٱلۡعِهۡنِ ٱلۡمَنفُوشِ
awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu
Surah Al-Qaria, Verse 5
فَأَمَّا مَن ثَقُلَتۡ مَوَٰزِينُهُۥ
Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won
Surah Al-Qaria, Verse 6
فَهُوَ فِي عِيشَةٖ رَّاضِيَةٖ
o si maa wa ninu isemi t’o yonu si
Surah Al-Qaria, Verse 7
وَأَمَّا مَنۡ خَفَّتۡ مَوَٰزِينُهُۥ
Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye
Surah Al-Qaria, Verse 8
فَأُمُّهُۥ هَاوِيَةٞ
Hawiyah si ni ibugbe re
Surah Al-Qaria, Verse 9
وَمَآ أَدۡرَىٰكَ مَا هِيَهۡ
Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee
Surah Al-Qaria, Verse 10
نَارٌ حَامِيَةُۢ
(Ohun ni) Ina gbigbona gan-an
Surah Al-Qaria, Verse 11