Surah Quraish - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
لِإِيلَٰفِ قُرَيۡشٍ
(Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo
Surah Quraish, Verse 1
إِۦلَٰفِهِمۡ رِحۡلَةَ ٱلشِّتَآءِ وَٱلصَّيۡفِ
(Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru
Surah Quraish, Verse 2
فَلۡيَعۡبُدُواْ رَبَّ هَٰذَا ٱلۡبَيۡتِ
Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii
Surah Quraish, Verse 3
ٱلَّذِيٓ أَطۡعَمَهُم مِّن جُوعٖ وَءَامَنَهُم مِّنۡ خَوۡفِۭ
Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya
Surah Quraish, Verse 4