Surah Al-Ikhlas - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
قُلۡ هُوَ ٱللَّهُ أَحَدٌ
So pe: "Oun ni Allahu, Okan soso
Surah Al-Ikhlas, Verse 1
ٱللَّهُ ٱلصَّمَدُ
Allahu ni Asiwaju (ti eda ni bukata si, ti Oun ko si ni bukata si won)
Surah Al-Ikhlas, Verse 2
لَمۡ يَلِدۡ وَلَمۡ يُولَدۡ
Ko bimo. Won ko si bi I
Surah Al-Ikhlas, Verse 3
وَلَمۡ يَكُن لَّهُۥ كُفُوًا أَحَدُۢ
Ko si si eni kan ti o jo O." eyi ni a mo si “robbu-ssamowat wal-’ard wa mo baenahumo”. Idi niyi ti a o fi tumo “Allahu” si “Olohun”. Ninu ede Yoruba ko fee si itumo ti a fokan bale si fun oro-oruko nla naa “Allahu” afi lilo oro-oruko kan eyi ti awon Yoruba maa n lo ni ojoun ana fun “Olohun”. Sise bee si maa mu ariyanjiyan lowo. Nitori naa
Surah Al-Ikhlas, Verse 4