Surah Al-Ikhlas - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
قُلۡ هُوَ ٱللَّهُ أَحَدٌ
Sọ pé: "Òun ni Allāhu, Ọ̀kan ṣoṣo
Surah Al-Ikhlas, Verse 1
ٱللَّهُ ٱلصَّمَدُ
Allāhu ni Aṣíwájú (tí ẹ̀dá ní bùkátà sí, tí Òun kò sì ní bùkátà sí wọn)
Surah Al-Ikhlas, Verse 2
لَمۡ يَلِدۡ وَلَمۡ يُولَدۡ
Kò bímọ. Wọn kò sì bí I
Surah Al-Ikhlas, Verse 3
وَلَمۡ يَكُن لَّهُۥ كُفُوًا أَحَدُۢ
Kò sì sí ẹnì kan tí ó jọ Ọ́." èyí ni a mọ̀ sí “rọbbu-ssamọ̄wāt wal-’ard wa mọ̄ baenahumọ̄”. Ìdí nìyí tí a ò fi túmọ̀ “Allāhu” sí “Ọlọ́hun”. Nínú èdè Yorùbá kò fẹ́ẹ̀ sí ìtúmọ̀ tí a fọkàn balẹ̀ sí fún ọ̀rọ̀-orúkọ ńlá náà “Allāhu” àfi lílo ọ̀rọ̀-orúkọ kan èyí tí àwọn Yorùbá máa ń lò ní ọjọ́un àná fún “Ọlọ́hun”. Ṣíṣe bẹ́ẹ̀ sí máa mú àríyànjiyàn lọ́wọ́. Nítorí náà
Surah Al-Ikhlas, Verse 4