Surah An-Nisa Verse 103 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaفَإِذَا قَضَيۡتُمُ ٱلصَّلَوٰةَ فَٱذۡكُرُواْ ٱللَّهَ قِيَٰمٗا وَقُعُودٗا وَعَلَىٰ جُنُوبِكُمۡۚ فَإِذَا ٱطۡمَأۡنَنتُمۡ فَأَقِيمُواْ ٱلصَّلَوٰةَۚ إِنَّ ٱلصَّلَوٰةَ كَانَتۡ عَلَى ٱلۡمُؤۡمِنِينَ كِتَٰبٗا مَّوۡقُوتٗا
Nigba ti e ba pari irun, ki e se (gbolohun) iranti Allahu ni iduro, ijokoo ati idubule yin. Nigba ti e ba si fokan bale (iyen nigba ti e ba wonu ilu), ki e kirun (ni pipe). Dajudaju irun kiki je oran-anyan ti A fi akoko si fun awon onigbagbo ododo